Lech Wałęsa
Ìrísí
Lech Wałęsa | |
---|---|
Aare ile Polandi | |
In office 22 December 1990 – 22 December 1995 | |
Alákóso Àgbà | Tadeusz Mazowiecki, Jan Krzysztof Bielecki, Jan Olszewski, Waldemar Pawlak, Hanna Suchocka, Józef Oleksy |
Asíwájú | Wojciech Jaruzelski (in country) Ryszard Kaczorowski (in exile) |
Arọ́pò | Aleksander Kwaśniewski |
1st Chairman of Solidarity | |
In office 1980 – 12 December 1990 | |
Asíwájú | N/A |
Arọ́pò | Marian Krzaklewski |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹ̀sán 1943 Popowo, Poland) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Solidarity |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Danuta Wałęsa |
Profession | Electrician |
Lech Walesa ( [ˈlɛx vaˈwɛ̃sa] (ìrànwọ́·info); ojoibi 29 September 1943) je oloselu omo orile-ede Polandi, alakitiyan tele fun egbe irepo onisowo ati eto omo eniyan. O gba Ebun Nobel fun iwa alafia ni 1983, o si je Aare ile Polandi lati 1990 titi di 1995.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |