Òkun Arábíà
Ìrísí
Òkun Arábíà Arabian Sea | |
---|---|
Coordinates | 15°55′10″N 63°54′22″E / 15.91944°N 63.90611°ECoordinates: 15°55′10″N 63°54′22″E / 15.91944°N 63.90611°E |
Max. width | 2,400 km (1,500 mi) |
Surface area | 3,862,000 km2 (1,491,000 sq mi) |
Max. depth | 4,652 m (15,262 ft) |
Okun Arabia (Sanskrit: सिन्धु सागर, pipe: Sindhu Sagar; Lárúbáwá: بحر العرب, pipe: Baḥr al-'Arab; Marathi: अरबी समुद्र, pipe: Arabi samudra; Malayalam: അറബിക്കടൽ, pipe: Aṟabikkaṭal) je ara Okun India to jamo India ni ilaorun, ni ariwa mo Pakistan ati Iran, ni iwoorun mo Erekusuile Arabia, ni guusu, ni die, mo ila larin Cape Guardafui, ojuile ariwa-ilaorun Somalia, Socotra, ati Kanyakumari (Cape Comorin) ni India.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |