Baruch Spinoza
Baruch de Spinoza | |
---|---|
Orúkọ | Baruch de Spinoza |
Ìbí | Amsterdam, Dutch Republic | Oṣù Kọkànlá 24, 1632
Aláìsí | February 21, 1677 The Hague, Dutch Republic | (ọmọ ọdún 44)
Ìgbà | 17th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Rationalism, founder of Spinozism |
Ìjẹlógún gangan | Ethics, Epistemology, Metaphysics |
Àròwá pàtàkì | Panentheism, Pantheism, Determinism, Deism, neutral monism, intellectual and religious freedom / separation of church and state, Criticism of Mosaic authorship of some books of the Hebrew Bible, Political society derived from power, not contract |
Ipa látọ̀dọ̀
| |
Ìpa lórí
|
Baruch Spinoza (Hébérù: ברוך שפינוזה Baruch Shpinoza, Pọrtugí: Bento de Espinosa, Látìnì: Benedictus de Spinoza) to di Benedict Spinoza (November 24, 1632 – February 21, 1677) je omo Portogi ara Hollandi elesin Ju amoye.[1] Pelu opolo onisayensi to ni, bi ise Spinoza se lagbara to ati se pataki to ko han titi ki o to ku. Loni, o je gbigba bi ikan ninu awon aselaakaye olokiki[2] imoye orundun 17k, to se ipilese fun Olaju orundun 18k[2] ati iseagbewo bibeli odeoni.[2] Nitori iwe re Ethics, to jade leyin iku re, ninu ibi to ti lodi si iseonimeji okan-ara Descartes, Spinoza je gbigba bi ikan ninu awon amoye pataki ninu Imooye apaiwoorun. Amoye ati akoitan Georg Wilhelm Friedrich Hegel so nipa gbogbo awon amoye igbalode pe, "E le je Asespinosa tabi ki e mo je amoye rara."[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]