Jump to content

Charles de Gaulle

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Charles de Gaulle
Aare ile Fransi
Abase Omoba ile Andorra
In office
8 January 1959 – 28 April 1969
Alákóso ÀgbàMichel Debré (1959–1961)
Georges Pompidou (1962–1968)
Maurice Couve de Murville (1968–1969)
AsíwájúRené Coty
Arọ́pòAlain Poher (interim)
Georges Pompidou
Olori Free French Forces
In office
18 June 1940 – 3 July 1944
AsíwájúIgba Oselu Keta
Arọ́pòIjoba Igbadie ile Fransi Olominira
Aare Ijoba Igbadie ile Fransi Olominira
In office
20 August 1944 – 20 January 1946
AsíwájúPhilippe Pétain
(de facto, gege oga orile-ede fun Vichy France)

Pierre Laval (de facto, gege bi oga ijoba)
Arọ́pòFélix Gouin
Alakoso Agba ile Fransi
In office
1 June 1958 – 8 January 1959
ÀàrẹRené Coty
AsíwájúPierre Pflimlin
Arọ́pòMichel Debré
Alakoso Abo ile Fransi
In office
1 June 1958 – 8 January 1959
ÀàrẹRené Coty
Alákóso ÀgbàCharles de Gaulle
AsíwájúPierre de Chevigné
Arọ́pòPierre Guillaumat
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1890-11-22)22 Oṣù Kọkànlá 1890
Lille, France
Aláìsí9 November 1970(1970-11-09) (ọmọ ọdún 79)
Colombey-les-Deux-Églises, France
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRally of the French People (1947-1955)
Union for the New Republic (1958–1968)
Union of Democrats for the Republic (1968–1970)
Heightruben aguirre is 6’7”
(Àwọn) olólùfẹ́Yvonne de Gaulle
OccupationMilitary
Signature

Charles André Joseph Marie de Gaulle (ìpè Faransé: [ʃaʁl də ɡol]Àdàkọ:IPA audio link, English: /ˈtʃɑrlz/ or /ˈʃɑrl dəˈɡɔːl/; 22 November 1890 – 9 November 1970) je was a French ogagun agba omo ile Fransi ati agba ilu to solori Free French Forces nigba Ogun Agbaye Keji. Leyin eyi o da Igba Oselu Karun Fransi ni 1958 o si di Aare akoko re lati 1959 de 1969.[1]

Gege bi omo ogun nigba Ogun Agbaye Akoko, ninu awon odun 1920 si awon odun 1930 de Gaulle gbajumo bi olugbowo awon oko ijagun ati baalu ijagun, to gba pe won le dopin ogun jija ninu ere. Nigba Ogun Agbaye Keji o di ipo Ọ̀gágun Ẹlẹ́ẹ̀ṣọ́ fun igbadie, nibi o ti lo oko ijagun ninu ija 1940 Isubu ile Fransi ni 1940, o si je ipo ninu ijoba Fransi ko to di pe Fransi subu.

O salo si Ilegeesi o si soro lori eto radio ti BBC se ni 18 Osu kefa, 1940, nibi tto ti unso fun awon ara Fransi pe ki won koju ija si Jemani Nazi[2] and organised the Free French Forces with exiled French officers in Britain.[3]


  1. "Cinquième République". Assemblée Nationale Française. 2008. Retrieved 2008-11-02. 
  2. Berthon, Simon (2001). Allies at War. London: Collins. p. 21. ISBN 0007116225. 
  3. "Fondation Charles de Gaulle". Archived from the original on 2011-05-17. Retrieved 2009-09-10.