Ikú ọmọ ọwó (Infant mortality)
Ìrísí
Ikú ọmọ ọwọ́ jẹ́ ikú tí ọmọ ọwọ́ máa ń kú kí ó tó tó ọmọ ọdún kan.[1] Iye ìṣẹ̀lẹ̀ ikú ọmọ ọwọ́ nínú ètò ìkànìyàn ni à ń pè lédè òyìnbó ní infant mortality rate (IMR), èyí ni iye àwọn ọmọ ọwọ́ ọjọ́ orí wọn kò tó ọdún kan tí wọ́n fi kú, nínú ẹgbẹ̀rún kan àwọn ọmọ tí wọ́n bí ní àbíyè nínú ọdún kan.[1] Bakan naa, a tún lè pe iye ikú ọmọ ọwọ́, (Infant mortality rate) ní iye ikú ọmọ ọwọ́ tó kéré sí ọdún márùn-ún (under-five mortality rate) , ní àfiwé rẹ̀ pẹ̀lú ikú àwọn ọmọ ọwọ́ tí ọjọ́ orí wọn kò tó ọdún márùn-ún.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Infant Mortality | Maternal and Infant Health | Reproductive Health | CDC". www.cdc.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-09-08. Retrieved 2023-04-07.
- ↑ "Under-Five Mortality". UNICEF. https://data.unicef.org/topic/child-survival/under-five-mortality/.