Lee Grant
Lee Grant | |
---|---|
Grant in 1967 | |
Ọjọ́ìbí | Lyova Haskell Rosenthal October 31, during the mid-1920s[lower-alpha 1] (age 97–99). New York City, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Neighborhood Playhouse School of the Theatre Actors Studio |
Iṣẹ́ | Actress and director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1933–present |
Olólùfẹ́ | Arnold Manoff (m. 1951; div. 1960) Joseph Feury (m. 1970) |
Àwọn ọmọ | 2, including Dinah Manoff |
Lee Grant (orúkọ àbísọ ni Lyova Haskell Rosenthal tíwọ́n bí ní October 31, ní àárín 1920)[lower-alpha 1] jẹ́ òṣèré ilé Améríkà, Olùdarí Eré àti ẹni tí ó ń ṣe iṣé Documentary. Eré àkọkọ rẹ ní èyí tí o ṣe ọmọde tí ń Fẹ́wọ́ nínú eré Detective Story tí William Wyler ṣe Adarí eré náà ni 1951, àwọn tí wọn sì kópa náà ní Kiri Douglas àti Eleanor Parker. Ìkópa rẹ̀ ninu eré yìí ní ọ jẹ́ kí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí Best Supporting Actresses lati lẹ̀ gba Àmì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì/ Oscar, ó sí gbà àmi ẹ̀yẹ Best Actress ní Cannes film Festivals Award. Ní ọdún 1952, ó wá lára àwọn mẹwàá tí Hollywood yóò fún ọdún méjìlá. Amò leyin èyí ní ó máa ń ṣe awọn eré ìtàgè kékéékèké tàbí iṣé Olúkóni ní ìgbà náà. Èyí náà mú kí óun àti ọkọ rẹ̀ wà ní ìpínyà. Ní àsìkò yìí Grant ṣe awọn eré ìtàgè. Ní ọdún 1963 ní Hollywood tó pé pada láti lè tẹsiwaju nínú iṣẹ eré rẹ̀ . Ó tí kópa nínú eré mọ́kànlèládọ́rin eré ọlọ́sọ́ọ̀sẹ̀ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Peyton Place lati ọdún 1965 sí 1966, àwọn eré mìíràn tí ó jẹ́ Olú òṣèré ní "Valley of Dolls" àti "In the heat of the Night ní 1967, àti Shampoo ní 1975, èyí tí o sí gbà àmi ẹ̀yẹ Oscar fún eré náà. Ní ọdún 1964 ó gbà Àmi ẹyẹ́ "Onje" fún ìkópa rẹ̀ nínú eré "The Maids. Nígbà tí ó ń ṣe iṣé eré gbogbo wọnyi ó wà lára àwọn tí wọ́n yàn ní ẹ̀mẹfà láti gba àmì ẹ̀yẹ "Emmy" ní ọdún 1966 sí 1933, èyí tí ó sí gbà Ẹbùn àmì ẹ̀yẹ náà ní ẹ̀ẹ̀mejì. Ní ọdún 1986, ọ darí òun àkójọpọ̀ kan Documentary tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ "Down and Out ìn America" èyí tí ó wà ni ìsopọ̀ pẹlú Academy Awards for heat Documentary Feature, ní ọdún yẹn bákan náà ni ọ gba àmì ẹ̀yẹ Directires Guild Of America fún eré Nobody's Child.
Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lee Grant tí àbísọ rẹ̀ njẹ Lyova Haskell Rosenthal[1][2] ní Manhattan, ó jẹ́ ọmọ kàn ṣoṣo tí Witia (nee Haskell), tí ó jẹ́ oṣiṣẹ ijoba tí ó ń mójú tó àwọn ọmọdé, tí bàbá rẹ̀ sí jẹ Abraham Wa. Rosenthal, tí ó jẹ́ Olùkọni àti Òǹtalẹ́. Wọn bí bàbá rẹ̀ sí Newyork, tí àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ àwọn ará ìlú New, ìyá bàbá Lee grant jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Russia tí ó jé Jew.[3] Awọn Òbí rẹ̀ ń gbé 706 Riverside Drive ni Hamilton Heights ni Manhattan.[citation needed] Ọjọ́ ìbí Lee je àríyànjiyàn sùgbón oṣù tí wọn bí ní ọjọ kọkanlelógbọ̀n, oṣù kẹwàá tí ọdún tí wọn bí wá láàrin 1925 sí 1931, Amò gẹ́gẹ́ bí òun tí ìkànìyàn sọ, wọn bí Leè ní 1925 tàbí ,1926, ṣugbọn iṣẹ tí Grant Yan láàyò àti pé ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọn Yàn fún Àmì Ẹ̀yẹ Oscar wọn pinnu pé ọdún tí wọn bí máa jẹ 1927.[lower-alpha 1]
Grant kọ́kọ́ kọ orín àkọkọ ní Franco Leonil Oracohok ní Metropolitan Opera ni 1931.[4][5] and later joined the American Ballet as an adolescent.[6] Ó lọ sí ilé ẹkọ fún àwọn tí wọn ní ìfẹ fún iṣẹ ọnà Arts Students League of New York tí wọn pè ní Juliard School of Music, The High School of Music àti George Washington High School tí gbogbo àwọn ilé ẹkọ yìí wà ní New York. Grant jáde ilé ẹkọ gíga, lẹyìn tí ó jáde ní ọ gbà àmi ẹyẹ ẹkọ Ọ̀fẹ́ sí Neighborhood Playhouse School of the Theatre ní bí tí ó tí kò ní ọ̀dọ Sanford Meissner. Grant tún ni tẹ̀siwájú lẹnu ẹkọ rere ni Ita Hagen ní HB studio.[7] Lẹyìn èyí ó lọ sí Actors Studio ní New York.
Filmography
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Actress
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Director
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Production | Notes |
---|---|---|
1973 | The Shape of Things | TV special |
1975 | For the Use of the Hall | TV film |
1976 | The Stronger | Short film |
1980 | Tell Me a Riddle | Feature film |
1981 | The Willmar 8 | Documentary film |
1983 | When Women Kill | Documentary film (also narrator) |
1984 | A Matter of Sex | TV film |
1985 | What Sex Am I? | Documentary film (also narrator) |
ABC Afterschool Special | Episode: "Cindy Eller: A Modern Fairy Tale" | |
1986 | Nobody's Child | TV film DGA Award for Outstanding Directorial Achievement in Dramatic Specials |
Down and Out in America | Documentary film (also narrator) Academy Award for Best Documentary Feature | |
1989 | Battered | Documentary film (also narrator) |
Staying Together | Feature film | |
No Place Like Home | TV film | |
1992 | Women on Trial | Documentary film (also narrator) |
1994 | Seasons of the Heart | TV film |
Following Her Heart | TV film | |
Reunion | TV film | |
1997 | Say It, Fight It, Cure It | TV film |
Broadway Brawler | unfinished film | |
1999 | Confronting the Crisis: Childcare in America | TV film |
2000 | American Masters | Episode: "Sidney Poitier: One Bright Light" |
The Loretta Claiborne Story | TV film | |
2001 | The Gun Deadlock | TV film |
2004 | Biography | Episode: "Melanie Griffith" |
2000–2004 | Intimate Portrait | 43 episodes |
2005 | ... A Father... A Son... Once Upon a Time in Hollywood | TV film |
Awards and nominations
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Roberts, Jerry. Encyclopedia of Television Film Directors, Scarecrow Press, 1st edition (June 5, 2009), Amazon Digital Services, Inc; ASIN: B009W3C7E8
- ↑ Katz, Ephraim. The Film Encyclopedia, Harper Perennial (1998) p. 552; ISBN 0-06-273492-X
- ↑ Profile, forward.com; accessed September 9, 2014.
- ↑ Olin Downes. The Opera: Scotti Cheered as Chim-Fen in "L'Oracolo"-Tribute to Mme. Jeritza in "Cavalleria." November 24, 1931. The New York Times. "Hoo-Chee...Lyova Rosenthal"
- ↑ "Movie Memory Lee Grant 1976". New York Daily News. December 1, 2002. http://www.nydailynews.com/movie-memory-lee-grant-1976-article-1.495393.
- ↑ Gray, Spalding. Life Interrupted: The Unfinished Monologue, Random House (2005) p. 154
- ↑ HB Studio Alumni
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- All articles with unsourced statements
- Articles with unsourced statements from June 2021
- Articles with invalid date parameter in template
- Àwọn ẹlẹ́bùn Akádẹ́mì Obìnrin Òṣeré Dídárajùlọ 2k
- Pages with reference errors
- Pages with reference errors that trigger visual diffs