Owó-ẹ̀yìn
Ìrísí
Owó-ẹ̀yìn tàbí Ẹ̀gúnjẹ ni gbígba owó tàbí ẹ̀bùn mìíràn lọ́nà àìtó láti ṣẹ̀gbẹ̀ fúnni fún èyíkéyìí àǹfàní. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìwà àjẹbánu tó burú jáì. Àwọn ọ̀gá ilé-iṣẹ́, àwọn olórí, Aláṣẹ tàbí àwọn olóṣèlú ni aje ìwà ìbàjẹ́ yìí sáàbà máa ń sẹ́ lórí jùlọ. Àwọn àwọn Adájọ́, Ọ̀lọ́pàá àti àwọn agbófinró mìíràn a máa gba Ẹ̀gúnjẹ láti ṣẹ̀gbẹ̀ fún ọ̀daràn tàbí láti gbẹ́bi fún aláre. Owó-ẹ̀yìn, tí a tún lè pè ní owó-àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tún máa ń wáyé àwọn ilé ẹ̀kọ́. Àwọn olùkọ́ mìíràn a máa Ẹ̀gúnjẹ láti fún akẹ́kọ̀ọ́ ní máàkì tàbí fún un ní èsì ìbéèrè ìdánwò. [1] [2] [3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "What is BRIBERY? definition of BRIBERY (Black's Law Dictionary)". The Law Dictionary. 2011-11-04. Retrieved 2020-01-22.
- ↑ "Bribery". LII / Legal Information Institute. 2016-07-25. Retrieved 2020-01-22.
- ↑ "Don't Pay for the Misdeeds of Others: Intro to Avoiding Foreign Third-Party FCPA Liability". Perkins Coie. Archived from the original on 2014-03-16. Retrieved 2020-01-22.
- ↑ "African corruption 'on the wane'". BBC NEWS. 2007-07-10. Retrieved 2020-01-22.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |