Jump to content

Ryutaro Hashimoto

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ryūtarō Hashimoto
橋本 龍太郎
Ryūtarō Hashimoto
Prime Minister of Japan
In office
11 January 1996 – 30 July 1998
MonarchAkihito
DeputyWataru Kubo
AsíwájúTomiichi Murayama
Arọ́pòKeizō Obuchi
Deputy Prime Minister of Japan
In office
2 October 1995 – 11 January 1996
Alákóso ÀgbàTomiichi Murayama
AsíwájúYōhei Kōno
Arọ́pòWataru Kubo
Minister of Finance
In office
28 January 1998 – 30 January 1998
Alákóso ÀgbàRyutaro Hashimoto
AsíwájúHiroshi Mitsuzuka
Arọ́pòHikaru Matsunaga
In office
10 August 1989 – 14 October 1991
Alákóso ÀgbàToshiki Kaifu
AsíwájúTatsuo Murayama
Arọ́pòToshiki Kaifu
Minister of Economy, Trade and Industry
In office
30 June 1994 – 11 January 1996
Alákóso ÀgbàTomiichi Murayama
AsíwájúEijiro Hata
Arọ́pòShunpei Tsukahara
Minister of Transport
In office
22 July 1986 – 6 November 1987
Alákóso ÀgbàYasuhiro Nakasone
AsíwájúHiroshi Mitsuzuka
Arọ́pòShintaro Ishihara
Minister of Health
In office
7 December 1978 – 9 November 1979
Alákóso ÀgbàMasayoshi Ōhira
AsíwájúTatsuo Ozawa
Arọ́pòKyoichi Noro
Member of the House of Representatives
In office
21 November 1963 – 11 September 2005
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1937-07-29)29 Oṣù Keje 1937
Sōja, Okayama, Japan
Aláìsí1 July 2006(2006-07-01) (ọmọ ọdún 68)
Shinjuku, Tokyo, Japan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLiberal Democratic Party
Àwọn ọmọGaku Hashimoto
Alma materKeio University

Ryutaro Hashimoto (橋本 龍太郎 Hashimoto Ryūtarō, tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1937[1] tí ó sì kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Japan tó di Alákòóso Àgbà ilẹ̀ Japan láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1996 títí di ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù keje ọdún 1998. Ó jẹ́ adarí ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó lágbára jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà kí ó tó di pé ó kọ ìṣèlú sílẹ̀. Nítorí ìtìjú, kò kópa nínú ìdìbò gbogboogbò tí orílẹ̀-èdè Japan ní ọdún 2005. Ó kú ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2006 ní ilé-ìwòsàn kan ní ìlú Tokyo.[2][3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]