Jump to content

Yukio Hatoyama

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yukio Hatoyama
鳩山 由紀夫
At the Metropolitan Museum of Art in New York.
Prime Minister of Japan
In office
16 September 2009 – 4 June 2010
MonarchAkihito
DeputyNaoto Kan
AsíwájúTaro Aso
Arọ́pòNaoto Kan
Member of the
Japanese House of Representatives
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
23 June 1986
Constituency9th Hokkaidō District
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kejì 1947 (1947-02-11) (ọmọ ọdún 77)
Bunkyō, Japan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Party (1998–present)
Other political
affiliations
Liberal Democratic Party (Before 1993)
New Party Sakigake (1993–1996)
Democratic Party[1] (1996–1998)
(Àwọn) olólùfẹ́Miyuki Hatoyama (1975–present)
Àwọn ọmọKiichiro Hatoyama
Alma materUniversity of Tokyo
Stanford University
ProfessionEngineer
Professor
WebsiteOfficial website

Yukio Hatoyama (鳩山由紀夫 Hatoyama Yukio?, ojoibi 11 February 1947) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Japan tó di Alákòóso Àgbà orílẹ̀-èdè Japan ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2009 (16 September 2009). Lọ́jọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 2010 (2 June 2010), Hatoyama kéde pé òun kọ̀wé fiṣẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Alákóso Àgbà .[2]