Argẹntínà
Argẹntínà Nínú ètò ìkànìyàn 1995, iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ajẹntínà (Argentiana) lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ (46 245 668). Èdè Pànyán-àn ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílè-èdè yìí lé ní ogún. Lára àwọn ogún èdè yìí ni àwọn èdẹ̀ tí wọ́n ń pè ní Àmẹ́rídíánà (Ameridian Languages) wà. Ara àwọn èdè. Àmérídíánà yìí ni ‘Guarani, Araucanian, Metaco àti Quechua’. Àwọn èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwọn tí ó wá se àtìpó ń sọ. Lára wọn ni èdè Ítílì (Ìtahàn) àti Jámánì (Herman). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i ní orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè fún òwò àgbáyé àti èdè àwọn tí ó ń ṣe àbẹ̀wò wá sí ibẹ̀ (International trade and tourism). Wọ́n ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí pẹ̀lú èdè Pànyán-àn.
Argentine Republic[1] República Argentina
| |
---|---|
Motto: En unión y libertad "In Unity and Freedom" | |
Orin ìyìn: Himno Nacional Argentino | |
Orthographic projection of Argentina | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Buenos Aires |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spanish |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 86.4% European (mostly Italian and Spanish) 8% Mestizo 4% Arab and East Asian 1.6% Amerindian [2][3] |
Orúkọ aráàlú | Argentine, Argentinian, Argentinean |
Ìjọba | Federal presidential republic |
Javier Milei | |
Victoria Villarruel | |
Horacio Rosatti | |
Independence from Spain | |
25 May 1810 | |
• Declared | 9 July 1816 |
Ìtóbi | |
• Total | 2,766,890 km2 (1,068,300 sq mi) (8th) |
• Omi (%) | 1.1 |
Alábùgbé | |
• 2022 estimate | 46 245 668 (33rd) |
• 2011 census | 40 117 096 |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $572.668 billion[4] (23rd) |
• Per capita | $14,408[4] (57th) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $324.767 billion[4] (31st) |
• Per capita | $8,171[4] (66th) |
Gini (2006) | 49[5] Error: Invalid Gini value |
HDI (2006) | ▲ 0.860 Error: Invalid HDI value · 46th |
Owóníná | Peso (ARS) |
Ibi àkókò | UTC-3 (ART) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC-2 (ART) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right (trains ride on the left) |
Àmì tẹlifóònù | +54 |
Internet TLD | .ar |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Article 35 of the "Constitution" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2007-11-22. Retrieved 2009-10-04. gives equal recognition to "United Provinces of the River Plate", "Argentine Republic" and "Argentine Confederation" and authorises the use of "Argentine Nation" in the making and enactment of laws
- ↑ Ben Cahoon. "Argentina". World Statesmen.org.
- ↑ "Encuesta Complementaria de Pueblos Indígenas 2004-2005". National Institute of Statistics and Census of Argentina. Archived from the original on 2008-06-11. Retrieved 2009-10-04. (Híspánì)
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 "Argentina". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.
- ↑ "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 2009-05-13. Retrieved 2009-09-01.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Argentina |