Alibéníà
Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Albáníà Republic of Albania Republika e Shqipërisë
| |
---|---|
Ibùdó ilẹ̀ Alibéníà (green) on the European continent (dark grey) — [Legend] | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Tirana |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Albanian1 |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 92% Albanians, 6% Greeks,[1][2] 2% others[3] |
Orúkọ aráàlú | Albanian |
Ìjọba | Orílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin |
• Ààrẹ | Ilir Meta |
Edi Rama | |
Formation | |
1190 | |
2 March 1444 | |
• Independence from the Ottoman Empire | 28 November 1912 |
2 December 1912 | |
28 November 1998 | |
Ìtóbi | |
• Total | 28,748 km2 (11,100 sq mi) (143rd) |
• Omi (%) | 4.7 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 3,195,000 [4] (136th) |
• 2001 census | 3,069,275 [5] |
• Ìdìmọ́ra | 111.1/km2 (287.7/sq mi) (63) |
GDP (PPP) | 2010 estimate |
• Total | $23.864 billion[6] |
• Per capita | $7,453[6] |
GDP (nominal) | 2010 estimate |
• Total | $11.773 billion[6] |
• Per capita | $3,677[6] |
Gini (2005) | 26.7[7] Error: Invalid Gini value |
HDI (2010) | ▲ 0.719[8] Error: Invalid HDI value · 64th |
Owóníná | Lek (ALL) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 355 |
ISO 3166 code | AL |
Internet TLD | .al |
|
Alibéníà (i /ælˈbeɪniə/ al-BAY-nee-ə, Àdàkọ:Lang-sq, Gheg Albanian: Shqipnia/Shqypnia), lonibise bi Orileominira ilẹ̀ Alibéníà (Àdàkọ:Lang-sq, pipe Àdàkọ:IPA-sq; Gheg Albanian: Republika e Shqipnísë), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani. O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo[a] ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ilaorun ati Girisi ni gusu ati gusuilaorun. O ni eti-omi ni egbe Omi-okun Adriatiki ni iwoorun, ati legbe Omi-okun Ionia ni gusiiworun. O fi iye to din ni 72 km (45 mi) jinna si Italy, nikoja Strait of Otranto to ja Adriatic Sea po mo Ionian Sea. Albáníà je omo egbe UN, NATO, Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe, Igbimo ile Europe, Agbajo Owo Agbaye, Agbajo Ipade Onimale be sini omo egbe lati ibere Isokan fun Mediteraneani. Albania ti fe di omo egbe Isokan Europe lati January 2003, be sini o ti toro lati di omo egbe lati 28 April 2009.[9]
Albáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na.[10] Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.[11][12][13]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedIJ
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedJP
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedcia
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedinstat2010
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named2001census
- ↑ 6.0 6.1 6.2 6.3 "Albania". International Monetary Fund. Retrieved 12 April 2011.
- ↑ "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 13 May 2009. Retrieved 1 September 2009.
- ↑ "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010.
- ↑ "Albania applies for EU membership". BBC News. 28 April 2009. http://news.bbc.co.uk/2/hi/europe/8023127.stm. Retrieved 29 April 2009.
- ↑ CIA – The World Factbook Archived 2020-05-15 at the Wayback Machine. Àdàkọ:WebCite
- ↑ Reports: Poverty Decreases In Albania After Years Of Growth.Dow Jones Newswires, 201-938-5500. Nasdaq.com
- ↑ Albania plans to build three hydropower plants.People's Daily
- ↑ Strong GDP growth reduces poverty in Albania-study. Reuters. Forbes.com