Angola
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà Republic of Angola República de Angola (Portuguese) Repubilika ya Ngola (Kikongo, Kimbundu, Umbundu) | |
---|---|
Olùìlú | Luanda |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Potogí |
Lílò national languages | Kikongo, Chokwe, Umbundu, Kimbundu, Ganguela, Kwanyama |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2000) | 37% Ovimbundu 25% Ambundu 13% Bakongo 22% ará Áfríkà míràn 2% Mestiço 1% ará Europe |
Orúkọ aráàlú | ará Àngólà |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan oníàrẹ |
• Ààrẹ | João Lourenço |
Bernito de Sousa | |
Aṣòfin | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ìlómìnira | |
• látọwọ́ Pọ́rtúgàl | 11 November 1975 |
Ìtóbi | |
• Total | 1,246,700 km2 (481,400 sq mi) (23k) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• 2014 census | 25,789,024[1] |
• Ìdìmọ́ra | 20.69/km2 (53.6/sq mi) (199th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $115.679 billion[2] (64k) |
• Per capita | $5,894[2] (107k) |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $100.948 billion[2] (61st) |
• Per capita | $5,144[2] (91k) |
Gini (2000) | 59[3] Error: Invalid Gini value |
HDI (2011) | ▲0.486 Error: Invalid HDI value · 148k |
Owóníná | Kwanza (AOA) |
Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (kòsí) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | +244 |
ISO 3166 code | AO |
Internet TLD | .ao |
Àngólà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: República de Angola, pípè [ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla];[4] Kikongo, Kimbundu, Umbundu: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ Namibia ní gúsù, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò ní àríwá, àti Zambia ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. Luanda ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko òde Kàbíndà ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àngólà di ileamusin Portugal ni 1884 leyin Ipade Berlin. O gba ilominira ni odun 1975 leyin ogun itusile. Ko pe leyin ilominira ni ogun abele sele lati 1975 de 2002. Àngólà ni opo alumoni ati petroliomu, be sini okowo re ti ungbera soke pelu iwon eyoika meji lati odun 1990, agaga lateyin igba ti ogun abele wa sopin. Sibesibe opagun ijaye si kere gidigidi fun opo alabugbe, be sini ojo ori ati iye ọ̀fọ̀ ọmọwọ́ ni Angola je awon eyi to buru julo lagbaye.[5]
Jeografi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okowo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Governo de Angola - page 89
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "Angola". International Monetary Fund. Retrieved 17 April 2012.
- ↑ "Gini Index". World Bank. Retrieved 2 March 2011.
- ↑ This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written
- ↑ (Gẹ̀ẹ́sì) Life expectancy at birth Archived 2018-12-29 at the Wayback Machine. www.cia.gov (2009)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |